Skip to main content

Posts

Showing posts from December, 2018

Fallow Ground

For moments Land left uncultivated  For seasonless season  Pasture left unplowed  Left lone; dormant field In ponderous dilapidation  There grass grows  In fistful profusion  Asleep solid soil  Clad in fruitless tares  Pachydomatous plain Array in thorny grass  O fallow ground! In desolation; for how long Will you live and reign As prodigal wasteland?  Break up your fallowness O fallow ground! Hark now Abandon not the Ìlèdú  In huge and hefty devastation  Unclog firmly today  Sterile, barren grains And plough and plant  Luxuriant crops  For you to reap aplenty  In cordial clemancy 

Ọ̀LẸ

Ọ̀lẹ yìí sùn lọ́ọrí Ọ̀lẹ yìí sùn funfun Ẹ wa bá mii jíń òle Pé ojuúmó ti mọ́ Ẹ wa bá mi soofún òle Pé òwúrò lọ jó ẹni a ríre Ẹ bá mi soofún pé Ẹni á gòkè láyé Níí láti tepá mósé Ẹni á wọ bàtà dídún láyé Níí láti sẹ́ ara rẹ̀ lóorun Emá gbàgbé láti wí fún pèé Òsìn níí gbẹ̀yìn òle Ẹni óò bá múra sí iṣé Irú won níí di akóbàtà Fún egbé Ẹni óò bá múra sí isé Irúu won níi di ògárá ọlọ́ṣà Lọ́la Ẹni ó bá mú ra sí isé Irúu won níi di jàndùkú Síìgboro Ẹni ó bá mú ra sí isé Irúu won níí di ẹni yẹpẹrẹ Láwùjọ Òlẹ!  Ìbá dára púpọ̀ kó o dìde Lórí àkéte àìníkan ṣe lóòní Ìbá dára kó o músé rẹ Lọ́ọ̀ kún kún dùn O bá múra sí iṣẹ́ Koò ba dii ẹni ẹ̀yẹ àti ẹni pàtàkì Lóla O bàá ṣíṣẹ́ kárakára lóòwúrọ̀ Kíí ọjọ́ alẹ́ le fún ọ ní 'simi Ọ̀lẹ! Òwúrọ̀ lọjọ́ ẹní má ríre ©' Jẹ́nyọ̀ Ẹniọlá