For moments Land left uncultivated For seasonless season Pasture left unplowed Left lone; dormant field In ponderous dilapidation There grass grows In fistful profusion Asleep solid soil Clad in fruitless tares Pachydomatous plain Array in thorny grass O fallow ground! In desolation; for how long Will you live and reign As prodigal wasteland? Break up your fallowness O fallow ground! Hark now Abandon not the Ìlèdú In huge and hefty devastation Unclog firmly today Sterile, barren grains And plough and plant Luxuriant crops For you to reap aplenty In cordial clemancy
Ọ̀lẹ yìí sùn lọ́ọrí Ọ̀lẹ yìí sùn funfun Ẹ wa bá mii jíń òle Pé ojuúmó ti mọ́ Ẹ wa bá mi soofún òle Pé òwúrò lọ jó ẹni a ríre Ẹ bá mi soofún pé Ẹni á gòkè láyé Níí láti tepá mósé Ẹni á wọ bàtà dídún láyé Níí láti sẹ́ ara rẹ̀ lóorun Emá gbàgbé láti wí fún pèé Òsìn níí gbẹ̀yìn òle Ẹni óò bá múra sí iṣé Irú won níí di akóbàtà Fún egbé Ẹni óò bá múra sí isé Irúu won níi di ògárá ọlọ́ṣà Lọ́la Ẹni ó bá mú ra sí isé Irúu won níi di jàndùkú Síìgboro Ẹni ó bá mú ra sí isé Irúu won níí di ẹni yẹpẹrẹ Láwùjọ Òlẹ! Ìbá dára púpọ̀ kó o dìde Lórí àkéte àìníkan ṣe lóòní Ìbá dára kó o músé rẹ Lọ́ọ̀ kún kún dùn O bá múra sí iṣẹ́ Koò ba dii ẹni ẹ̀yẹ àti ẹni pàtàkì Lóla O bàá ṣíṣẹ́ kárakára lóòwúrọ̀ Kíí ọjọ́ alẹ́ le fún ọ ní 'simi Ọ̀lẹ! Òwúrọ̀ lọjọ́ ẹní má ríre ©' Jẹ́nyọ̀ Ẹniọlá